80 likes | 682 Views
EDE YORUBA JS3 OSE KEJI. APOLA-ORUKO. APOLA-ORUKO. Ni oro tabi akojopo oro ti a le ri ni ipo oluwa tabi ipo abo ninu gbolohun . Bi apeere : Bolu ti jade ile-iwe . Mo je ibepe . Iwo feran ise . IHUN APOLA-ORUKO. Apola-oruko eleyo oro kan .
E N D
EDE YORUBAJS3OSE KEJI APOLA-ORUKO
APOLA-ORUKO Ni orotabiakojopooroti a le riniipooluwatabiipoaboninugbolohun. Bi apeere: Boluti jade ile-iwe. Mo je ibepe. Iwoferanise. IHUN APOLA-ORUKO. Apola-orukoeleyoorokan. a. Oro-orukokanniipooluwatabiabo. bi apeere: Ade je isu. Sade pa ejo. Ibadanni mo lo.
Oro aropo-orukokanniipooluwatabiabo. Bi apeere: Mojeun. Ewa mu omi. Akin tiriwon. Oro Aropo-afarajorukoniipooluwa. Bi apeere: Emiko mo. Ounni o feri. Awonomo n ko? Apola-orukoti o je akojopooro. Oro-orukoakokoni o maa n je orinigbatiawonyookuyoo je eyan. Bi apeere: Iseolukowu mi. orieyan
2. Ade obani mo de. 3. Mo lo siOja ale OrieyanOrieyan
IseApola-oruko :- Isemeteetatioro-oruko n se ninugbolohunniapola-oruko n se. Awonni; Oluwa: Ade jeun. Tolu pa eja. Isuni mo je. Abo: Iyaagba we gele. Bisi je isu. Mo lo siEko. Eyan: Ade olobeni o wa. AjaObani mo pa. O de adeOba.
Iseasetilewa. Iruisewoniapola-orukoti a falasi n se ninugbolohunwonyii:- Olu sun. Sade ponomi. Iseagbedara. Oluko n pewa. Wari mi niale.