180 likes | 486 Views
Welcome to today’s service…. I walk in the way of righteousness, along the paths of justice, bestowing wealth on those who love me and making their treasuries full. – Proverbs 8: 20 - 21. 1. Hymn 156 - Yoruba.
E N D
Welcome to today’s service… I walk in the way of righteousness, along the paths of justice, bestowing wealth on those who love me and making their treasuries full. – Proverbs 8: 20 - 21
1. Hymn 156 - Yoruba • Olugbala awa ma tundeYonu si wa o Baba yeJesu Kristi OlugbalaGba wa logun ajakaiye. • A duro lori Kristi waKo wa ba ti nse li orunRan Maleka Re sokaleKa le bori esu laiye. (Amin)
Ope, ni fun Baba, Open ni fun Omo Re,Ope, ni fun Emi Mimo, Emi a yin Jesu. Halleluyah fun Baba, Halleluyah fu Omo ReHalleluyah fun Emi Mimo, Emi a yin Jesu. Hassanah fun Baba, Hossanah fun Omo ReHossanah fun Emi Mimo, Emi a yin Jesu. Ebenezer fun Baba, Ebenezer fun Omo ReEbenezer fun Emi Mimo, Emi a yin Jesu. (Amen) 2. Hymn 386 – Yoruba (117 Eng)
Three members’ prayers… With God All Things Are Possible! -- Matthew 19:26
Oh lift ye your heads high,Ye everlasting gatesThat we may raise thee up highYe everlasting door.Cr That the King of Glory might come in Come into His Holy house Who is this King of Glory? Jehovah is the King of Glory Who is this King of Glory? Jesus Christ the Redeemer. Oh crown him King all ye his peopleLet all the world crown him King,And with happiness worshiping him,Worship him with zealousness.Cr That the King of Glory might come in… 3. Hymn – 94 Eng (731 Yor.) • Power of the Holy Spirit’s ready,To be established within us,With sacred minds calling upon himCalling Him in His Holy houseCr That the King of Glory might come in… • With all benevolence and pure loveWorshiping our King who sees allHe who knows minds of everybodyWill hearken unto all our cries. Cr That the King of Glory might come in… (Amen).
Silent Prayer Therefore I say to you, all things for which you pray and ask, believe that you have received them, and they will be granted you. -- Mark 11:24
Agbara nla otito to ti sanmo meje waAgbara nla otito to ti sanmo meje waAgbara nla loje, Agbara nla lo jeAgbara nla otito to ti sanmo meje waAgbara isegun ni fun wa. Etan mole otito enyin Maleka MimoEtan mole otito enyin Maleka MimoOgo ni fun Baba, Ogo ni fun OmoEtan mole otito enyin Maleka MimoOgo ni fun oruko Re. Egbe ni fun esu ati fun ise owo reBaba ti gegun fun, Omo ti gegun funEgbe ni fun esu ati fun ise owo reEgbe ni fun awon to ntele. Amin. 4. Hymn 537 – Yoruba
1st Bible Lesson Proverbs 8:14-31 I love those who love me, and those who seek me find me. With me are riches and honor, enduring wealth and prosperity. – Proverbs 8: 17 - 18
Ojo na pe loni Ijo Mimo,cr Ro daju, Ijo Mimo Bawo lo ti wa di okan re si Jowo ro daju Ijo Mimo Eje Kristi Jesu iyebiye To mu irapada wa f’araiyeF’eni to ba gbagbo to se gbo ran Yio ri ‘ye ni ‘Jo Mimo. Iwo ha je ‘leke tabe ‘letan?cr Ro daju, Ijo Mimo… Ojukokoro ha ndamu re bi? cr Ro daju, Ijo Mimo… 5. Hymn 772 – Yoruba • Ikunsinu kan ha wa lokan re? cr Ro daju, Ijo Mimo… • Iwo ha le fi ise re sin Jesu?cr Jowo Ro daju, Ijo Mimo…Eje Kristi Jesu iyebiye To mu irapada wa f’araiyeF’eni to ba gbagbo to se gbo ran Yio ri ‘ye ni ‘Jo Mimo. Amin.
2nd Bible Lesson 2 Corinthians 9:6-15 Remember this: Whoever sows sparingly will also reap sparingly, and whoever sows generously will also reap generously. – 2 Corinthians 9:6
Nigbati fere Oluwa yio dun, Ti ise ki o si mo,A o pe ohun alaye ‘gun merin wa, Lati fi ise won han,Ni’waju Olugbala wa,Nigabti fere yio dun, Emi o wa nibecr Nigbati, fere yio dun lohun, Nigbati, fere yio dun lohun, Nigbati, fere yio dun lohun, Nigabti fere yio dun, Emi o wa nibe 6. Hymn 580 – Yoruba • Awa yio ma korin, Lat owuro titi dale,Awa yio ma f’Ogo fun Olorun, Olugbala yio ma pe,Gbogbo wa ni omo rere, cr Nigabti fere yio dun, Emi o wa nibe, etc. • Awa olurapada yio ‘fo, T’aro ki yio mu wa,Lati pade ‘Lugbala Jesu Kristi, Awa yio wa ni abe‘Ye Olorun titi aiye,Alleluyah ni orin wa yio ma je,cr Nigabti fere yio dun, Emi o wa nibe, etc. Amin.
The Sermon… That if you confess with your mouth, "Jesus is Lord," and believe in your heart that God has raised Him from the dead, you will be saved. -- Romans 10:9
Collection… Please remember… All collections are taken ONCE, followed by tithes and Chairmanship!
Thanks Offering… Enter into His gates with thanksgiving, And into His courts with praise. Be thankful to Him, and bless His name. – Psalms 100:4
7. Hymn 429 Yoruba • Iwo duro lasan laisise kanNigbati awon elomiran nsiseOju Oluwa nwo ise recr Awon Angeli Mimo nko won… • Logon o ti gbohun fere wipeTe do je boo, wakati na ti de’Oju saju, anu atijo d’opincr Awon Angeli Mimo nko won… Iba se rere tabi ibi Ere ise re ni iwo yio gba.Amin. • Ma sise lo, ma se wa isimi,Ma furugbin, Olukore mbo,Oju Oluwa nwo ise re,cr Awon Angeli Mimo nko won Iba se rere tabi ibi Ere ise re ni iwo yio gba.
Have a God blessed week!And a safe trip back home… … We give thanks to the God and Father of our Lord Jesus Christ, praying always for you. -(Colossians 1:3)