190 likes | 220 Views
Embrace the powerful message of Isaiah 35:1 and hymns in Yoruba and English. Find solace in the comforting words and prayers, reflecting on God's strength and mercy for salvation.
E N D
Welcome to today’s service… Say to them that are of a fearful heart, be strong, fear not, behold, your God will come with vengeance, even God with a recompense; he will come and save you. – Isaiah 35:
1. Hymn 541 - Yoruba • Mo ti sina, sinu ese, Ore Oluwa lori mi he,Oku fun mi lori igi, Ore Ofe Oga Ogo poju. • Mo ti sonu, sinu ese, Ore Oluwa lori mi he,Oku fun mi lori igi, Ore Ofe Oga Ogo poju. • Halleluyah; Halleluyah Ore Oluwa lori mi he,Oku fun mi lori igi, Ore Ofe Oga Ogo poju. (Amin)
Emi ba legberun ahon, Fiyin OlugbalaOgo Olorun oba mi, Isegun Ore recr Abi ko seun fun o, A oma se fun mi Eje re se fun, Eje re se fun mi. Jesu to soro mi dayo, Omu banuje tanOrin ‘yin lenu elese, Iye ati ileracr Abi ko seun fun o, A oma se fun mi. Baba mi at’Olorun mi, Fun mi ni ‘ranwo ReKi nle ro ka gbogbo aiye, Lola oruko Recr Abi ko seun fun o, A oma se fun mi. O korin odi gbohun Re, A foju ri gbalaOniro binuje yo ayo, Ara e ho fayocr Abi ko seun fun o, A oma se fun mi. (Amen) 2. Hymn 387 – Yoruba (117 Eng)
Three members’ prayers… With God All Things Are Possible! -- Matthew 19:26
Holy Spirit the Comforter Descend into our midstThou are the King of blessing We are expecting thee. For thou art the Almighty King Great King and benefactorOh King of spirit descend now We are expecting thee. King of mercy descend now Look on us with mercyWe thy children look unto thee Open thy door of mercy. Oh Holy King, benefactor Father send us blessingsFor thou art the Almighty Who blesses His children. King of mercy, O King of life Kindle thy light for usThou art the King full of light We are expecting thee. O Holy King, O King of light Descend and bless us nowFor thou art King of mercy We are expecting thee. Amen. 3. Hymn 41 - English
Silent Prayer Therefore I say to you, all things for which you pray and ask, believe that you have received them, and they will be granted you. -- Mark 11:24
Ma foya ni apa Jesu, Ko si ohun eru kan,Ina ti njo ko le sun mo o, Ogun esu ti di wiwo mole. Mo ro mo agbelebu Re Mo ka ohun gbogbo sasanMa beru ire okan mi, Ayo nbe ninu eje Jesu. 4. Hymn 537 – Yoruba - OVER -
Emi ko ni ju o sile, Jesu Olugbala mi,Ninu Re ni iye mi wa, Ire ni Olugbala mi. Ijo Mimo bu si ayo, Oko iyawo wa pelu Re,Ayo ni tire si ma yo, Ade iye na yio je tire. Amin. 4. Hymn 537 – Yoruba (Cont’d)
1st Bible Lesson Proverbs 11:24-31 Beat your plowshares into swords And your pruning hooks into spears; Let the weak say, "I am strong."' – Joel 3:10
Oluwa Olugbala, Oluwa Olugbala, Jehovah Olugbala, Yio si gbo ti wa. Oluwa Oba Iye Oluwa Oba Iye, Kristi Oba Imole, O mbe lodo wa. 5. Hymn 52 – Yoruba • E kepe Oba Ogo, E kepe Oba Mimo, E kepe Oba Iye Yio si gbo oro wa. • Oba ti ko gbagbe, Oba ti ko gbagbe,Oba ti ko gbagbe, Ijo Mimo re. - OVER -
Awon Angeli mbe, Awon Angeli mbe,Awon Angeli mbe, Ninu ayo nla. Iyin fun Oba Mimo, Iyin fun Oba nla,Ogo ni fun Oba nla, Fun ise Re ni. 5. Hymn 52 – Yoruba • E ke Halleluya, E ke Halleluya,E ke Halleluya, Pelu ife Mimo. Amin.
2nd Bible Lesson Luke 16:19-31 For it would have been better for them not to have known the way of righteousness, than having known it, to turn from the holy commandment delivered to them. – 2 Peter 2:21
6. Hymn 303 - Yoruba • Eda to mola ko si, Eda to mola ko si,Eda to mola ko si, Asan laiye nse. • Imo asan ni t’aiye, Imo asan ni t’aiye,Imo asan ni t’aiye, Asan laiye nse. • Sagbeke le Oluwa, Sagbeke le Oluwa,Sagbeke le Oluwa, Sagbeke re le. Amin.
The Sermon… That if you confess with your mouth, "Jesus is Lord," and believe in your heart that God has raised Him from the dead, you will be saved. -- Romans 10:9
Collection… Please remember… All collections are taken ONCE, followed by tithes and Chairmanship!
Thanks Offering… Enter into His gates with thanksgiving, And into His courts with praise. Be thankful to Him, and bless His name. – Psalms 100:4
Jehovah, Jesu Kristi, Michael Mimo, Oga ogun,Ijo Mimo mbe niwaju Re, Teru tedun okan wa,Lati saferi Emi Mimo, Ewa ogo Orun,Ibukun ati gbega, Ma se fi du wa. Ma bi si i, Si ma re si i, Ileri Re f’Abraham,Niwoyi odun titun, Iwo yio f’omo se re,Ileri yi fun Sarah, Jo muse f’awon agan,Ti nwon woju Re Baba, F’omo b’Isaki. Ninu okun pupa ni, Farao at’ogun re,Parun laigberi mo, Fun isimi okan Israel,Nigbati ‘reti dopin, Okun diyangbe ile,Nipa agbara iyanu yi, Sin wa de ‘nu iye. Ogbon, Imo, Oye Re, Gegebi ti Solomon,Igbega ati igbala Bi ti Josef’, Danieli,Imisi a ‘tohun Orun, Bi ti Paul, Samueli,Elmorijah, Olubukun, Se nwon ni ti ‘wa. 7. Hymn 406 - Yoruba - OVER -
Awa nse ireti Re, Gege b’Omo ileri,Ajo jumo jogun iye, Ainipekun ‘joba orun,Wa f’Emi orun s’atoko, Di wa l’amure agbara,Ka sise lailabawon, Si iye ainipekun. Amin. 7. Hymn 406 - Yoruba