190 likes | 640 Views
Welcome to today’s service…. Say to them that are of a fearful heart, be strong, fear not, behold, your God will come with vengeance, even God with a recompense; he will come and save you. – Isaiah 35:. 1. Hymn 541 - Yoruba.
E N D
Welcome to today’s service… Say to them that are of a fearful heart, be strong, fear not, behold, your God will come with vengeance, even God with a recompense; he will come and save you. – Isaiah 35:
1. Hymn 541 - Yoruba • Mo ti sina, sinu ese, Ore Oluwa lori mi he,Oku fun mi lori igi, Ore Ofe Oga Ogo poju. • Mo ti sonu, sinu ese, Ore Oluwa lori mi he,Oku fun mi lori igi, Ore Ofe Oga Ogo poju. • Halleluyah; Halleluyah Ore Oluwa lori mi he,Oku fun mi lori igi, Ore Ofe Oga Ogo poju. (Amin)
Emi ba legberun ahon, Fiyin OlugbalaOgo Olorun oba mi, Isegun Ore recr Abi ko seun fun o, A oma se fun mi Eje re se fun, Eje re se fun mi. Jesu to soro mi dayo, Omu banuje tanOrin ‘yin lenu elese, Iye ati ileracr Abi ko seun fun o, A oma se fun mi. Baba mi at’Olorun mi, Fun mi ni ‘ranwo ReKi nle ro ka gbogbo aiye, Lola oruko Recr Abi ko seun fun o, A oma se fun mi. O korin odi gbohun Re, A foju ri gbalaOniro binuje yo ayo, Ara e ho fayocr Abi ko seun fun o, A oma se fun mi. (Amen) 2. Hymn 387 – Yoruba (117 Eng)
Three members’ prayers… With God All Things Are Possible! -- Matthew 19:26
Baba palase lat’Orun wa, Ki gbogbo aiye si wariri, Fun ‘jo Mimo, lat’Orun wa, Ijo yi ni, yio we aiye mo, Aje, oso, yio wariri, L’abe agbara Mimo, yi, Awon Angeli si kun f’ayo, Iyanu, f’oko ikehin, Halleluya fun ise Oluwa. Igba ikehin na ti de, Kristi Jesu yio pada wa, Lati wa se ‘dajo aiye, Iku Re lori agbelebu,Eje ati omi to nsan Kuro ninu iha Mimo Re,Ko gbodo lo sori asan, Gbogbo oju yio si tun ri,Pelu awon Angeli Mimo Re. Kelese ronupiwada, F’ojo iwariri nla na Awon Angeli yio fun ipe, A o ka ile at’Orun, Okun yio d’ohun airi mo, Awon oku yio ji dide, Imiran pelu ayo nla, Imiran pelu ijiya, Elese yio wariri lojo na. Awon ‘toku foro Kristi, Awo t’oru Agbelebu Re, Nwon yio ji pelu ogo nla, A o wo won laso ogo, A ode won lade wura, Mariwo ope lowo won, Nwon yio fo pade Kristi, Are ki yio si fun won mo, Halleluya, li ohun orin won. Amin. 3. Hymn 176 - Yoruba
Silent Prayer Therefore I say to you, all things for which you pray and ask, believe that you have received them, and they will be granted you. -- Mark 11:24
Ma foya ni apa Jesu, Ko si ohun eru kan,Ina ti njo ko le sun mo o, Ogun esu ti di wiwo mole. Mo ro mo agbelebu Re Mo ka ohun gbogbo sasanMa beru ire okan mi, Ayo nbe ninu eje Jesu. 4. Hymn 537 – Yoruba - OVER -
Emi ko ni ju o sile, Jesu Olugbala mi,Ninu Re ni iye mi wa, Ire ni Olugbala mi. Ijo Mimo bu si ayo, Oko iyawo wa pelu Re,Ayo ni tire si ma yo, Ade iye na yio je tire. Amin. 4. Hymn 537 – Yoruba (Cont’d)
1st Bible Lesson Genesis 8:13-22 Beat your plowshares into swords And your pruning hooks into spears; Let the weak say, "I am strong."' – Joel 3:10
Let us unite, To praise Father Let us unite,To praise Fathercr For the last church He sent down Sing Hosanna, Shout Hosanna To the Lord God Trinity. Come Redeem us Lord of Celestial Come heal the sick Lord of Celestial 5. Hymn 12 – English • Conquer for us Lord of CelestialCome comfort us Lord of Celestial. • Have Mercy on us Lord of CelestialCome bless us all Lord of Celestial.Chorus: … (Amen)
2nd Bible Lesson Matthew 20:1-16 For it would have been better for them not to have known the way of righteousness, than having known it, to turn from the holy commandment delivered to them. – 2 Peter 2:21
6. Hymn 188 - Yoruba • Jesu Ku fun aiye, Jesu ku fun aiye,Aiye e yi pada o, Jesu ku fun aiye • Ese bori aiye, Ese bori aiye,Aiye e yi pado o Jesu ku fun aiye. Amin.
The Sermon… That if you confess with your mouth, "Jesus is Lord," and believe in your heart that God has raised Him from the dead, you will be saved. -- Romans 10:9
Collection… Please remember… All collections are taken ONCE, followed by tithes and Chairmanship!
Thanks Offering… Enter into His gates with thanksgiving, And into His courts with praise. Be thankful to Him, and bless His name. – Psalms 100:4
Jehovah, Jesu Kristi, Michael Mimo, Oga ogun,Ijo Mimo mbe niwaju Re, Teru tedun okan wa,Lati saferi Emi Mimo, Ewa ogo Orun,Ibukun ati gbega, Ma se fi du wa. Ma bi si i, Si ma re si i, Ileri Re f’Abraham,Niwoyi odun titun, Iwo yio f’omo se re,Ileri yi fun Sarah, Jo muse f’awon agan,Ti nwon woju Re Baba, F’omo b’Isaki. Ninu okun pupa ni, Farao at’ogun re,Parun laigberi mo, Fun isimi okan Israel,Nigbati ‘reti dopin, Okun diyangbe ile,Nipa agbara iyanu yi, Sin wa de ‘nu iye. Ogbon, Imo, Oye Re, Gegebi ti Solomon,Igbega ati igbala Bi ti Josef’, Danieli,Imisi a ‘tohun Orun, Bi ti Paul, Samueli,Elmorijah, Olubukun, Se nwon ni ti ‘wa. 7. Hymn 406 - Yoruba - OVER -
Awa nse ireti Re, Gege b’Omo ileri,Ajo jumo jogun iye, Ainipekun ‘joba orun,Wa f’Emi orun s’atoko, Di wa l’amure agbara,Ka sise lailabawon, Si iye ainipekun. Amin. 7. Hymn 406 - Yoruba