1 / 6

EDE YORUBA JS3 OSE KEJI

EDE YORUBA JS3 OSE KEJI. APOLA-ORUKO. APOLA-ORUKO. Ni oro tabi akojopo oro ti a le ri ni ipo oluwa tabi ipo abo ninu gbolohun . Bi apeere : Bolu ti jade ile-iwe . Mo je ibepe . Iwo feran ise . IHUN APOLA-ORUKO. Apola-oruko eleyo oro kan .

juliet
Download Presentation

EDE YORUBA JS3 OSE KEJI

An Image/Link below is provided (as is) to download presentation Download Policy: Content on the Website is provided to you AS IS for your information and personal use and may not be sold / licensed / shared on other websites without getting consent from its author. Content is provided to you AS IS for your information and personal use only. Download presentation by click this link. While downloading, if for some reason you are not able to download a presentation, the publisher may have deleted the file from their server. During download, if you can't get a presentation, the file might be deleted by the publisher.

E N D

Presentation Transcript


  1. EDE YORUBAJS3OSE KEJI APOLA-ORUKO

  2. APOLA-ORUKO Ni orotabiakojopooroti a le riniipooluwatabiipoaboninugbolohun. Bi apeere: Boluti jade ile-iwe. Mo je ibepe. Iwoferanise. IHUN APOLA-ORUKO. Apola-orukoeleyoorokan. a. Oro-orukokanniipooluwatabiabo. bi apeere: Ade je isu. Sade pa ejo. Ibadanni mo lo.

  3. Oro aropo-orukokanniipooluwatabiabo. Bi apeere: Mojeun. Ewa mu omi. Akin tiriwon. Oro Aropo-afarajorukoniipooluwa. Bi apeere: Emiko mo. Ounni o feri. Awonomo n ko? Apola-orukoti o je akojopooro. Oro-orukoakokoni o maa n je orinigbatiawonyookuyoo je eyan. Bi apeere: Iseolukowu mi. orieyan

  4. 2. Ade obani mo de. 3. Mo lo siOja ale OrieyanOrieyan

  5. IseApola-oruko :- Isemeteetatioro-oruko n se ninugbolohunniapola-oruko n se. Awonni; Oluwa: Ade jeun. Tolu pa eja. Isuni mo je. Abo: Iyaagba we gele. Bisi je isu. Mo lo siEko. Eyan: Ade olobeni o wa. AjaObani mo pa. O de adeOba.

  6. Iseasetilewa. Iruisewoniapola-orukoti a falasi n se ninugbolohunwonyii:- Olu sun. Sade ponomi. Iseagbedara. Oluko n pewa. Wari mi niale.

More Related