1 / 8

NIGERIAN LANGUAGE YORUBA 2 ND WEEK.

NIGERIAN LANGUAGE YORUBA 2 ND WEEK. IHUN GBOLOHUN GBOLOHUN. A.Orisi ihun gbolohun 1.Ihun nipa apola . Ihun nipa awe. IHUN GBOLOHUN. APOLA. AWE. GBOLOHUN. Apola oruko. Apola ise. 1.Mo. Lo si Eko. 2.Ode. N kun eran. D. Ihun nipa awe gbolohun

Download Presentation

NIGERIAN LANGUAGE YORUBA 2 ND WEEK.

An Image/Link below is provided (as is) to download presentation Download Policy: Content on the Website is provided to you AS IS for your information and personal use and may not be sold / licensed / shared on other websites without getting consent from its author. Content is provided to you AS IS for your information and personal use only. Download presentation by click this link. While downloading, if for some reason you are not able to download a presentation, the publisher may have deleted the file from their server. During download, if you can't get a presentation, the file might be deleted by the publisher.

E N D

Presentation Transcript


  1. NIGERIAN LANGUAGEYORUBA2ND WEEK. IHUN GBOLOHUN GBOLOHUN

  2. A.Orisiihungbolohun 1.Ihun nipaapola. Ihunnipa awe. IHUN GBOLOHUN APOLA AWE

  3. GBOLOHUN Apolaoruko Apolaise 1.Mo Lo siEko 2.Ode N kun eran

  4. D. Ihunnipa awe gbolohun Gbolohunonibo :eyi pin sionameji AWE GBLOHUN Olori awe gblohun Afarahe 1.Afarahe asaponle 2.Afarahe asodoruko 3.Afarahe asapejuwe

  5. E. Abuda awe gbolohun 1.Awe gbolohun le je ipedetionioluwaatiohuntioluwa se. Apeere:Adejoke mu omi. Awonakekoojeun. 2.O le nijuapolaorukoatiapolaisekookan lo. 3.Awe gbolohun le daduroki o niitumo.Apeere:Omieronaa mo. 4.Awe gbolohunmiranledadurokioniitumo. 5.Awe gbolohun le dadurobiiodidigbolohun,iru awe gbolohun bee ni a n peniolori awe gbolohun.Biapeere:Wongba,Ade mo. 6.Opolopo awongbolohun abode ni o le se isegbolohun,sugbonkii se gbogbo awe gbolohun lo le durobiigbolohun.

  6. Olori awe gbolohun:eyini awe gbolohunti o le daduro,ki o siniitumo Awe. Awe gbolohunafarahe:awegbolohunafaraheniapagbolhunonibotabialakanpotiko le Daduro. Orisi awe gbolohunafarahe. 1.AwegbolohunAsaponle. 2. Awe gbolohunAsapejuwe. 3.Awe gbolohunAsodoruko.

  7. IyatolaarinApolaati awe gbolohun. 1.Apola le nioro –isetabikiomani,dandannioroise fun awe gbolohun. 2.Apola ko le daduroki o fun waniitumokikunsugbon awe gbolohun le daduro. 3.Apola le waninu awe gbolohuntioniitumo. 4.Awe le je odidigbolohun to kun.

  8. ISE ASE TI LE WA. 1.Ki nigbolohun? 2.Ona melonigbawoihungbolohun?Soawononawonyii. 3.So abuda meta ti awe gbolohun le ni. 4.So orisi awe gbolohunti o wa,peluapeerekookan.

More Related