1 / 10

ISE ISENBAYE

ISE ISENBAYE. ISE AGBE ATI ISE ILU LILU. ORIKI ISE ISENBAYE. Ise isenbaye naa ni a mo si ISE ABINIBI. O je ise ti a jogun lati owo awon baba nla wa. APEERE ISE ISENBAYE Owo sise Ona sise Ope kiko Ise ila kiko Ise agbe , Ise ode, Ise ilu lilu , Ise agbede ,

linus-ware
Download Presentation

ISE ISENBAYE

An Image/Link below is provided (as is) to download presentation Download Policy: Content on the Website is provided to you AS IS for your information and personal use and may not be sold / licensed / shared on other websites without getting consent from its author. Content is provided to you AS IS for your information and personal use only. Download presentation by click this link. While downloading, if for some reason you are not able to download a presentation, the publisher may have deleted the file from their server. During download, if you can't get a presentation, the file might be deleted by the publisher.

E N D

Presentation Transcript


  1. ISE ISENBAYE ISE AGBE ATI ISE ILU LILU

  2. ORIKI ISE ISENBAYE • Iseisenbayenaani a mo si ISE ABINIBI. • O je iseti a jogunlatiowoawonbabanlawa • APEERE ISE ISENBAYE • OwosiseOnasiseOpekikoIseilakiko • Iseagbe , Ise ode, Iseilulilu, Iseagbede, • Isearodida, Iseirundidi

  3. . • AGBE AYE ATIJO • ORISIIRISII AGBE AYE ATIJO • AGBE ALAROJE– o n daokokekere fun ohunjejije. • Apeere ere oko re : ogede, agbado, isu. ege, eree, ataatiewebe. • AGBE OLOKO NLA- o n daokonlalatigbinohunjijeatiigiowobiikoko, ope, kofi, obi, orogbo, atiigiroba. • Won maa n lo eruatiiwofafun iseloko. • Awoniyawo, omoatiebinaamaa n ran won lowo. ISE AGBE • Iseagbe je iseokoriro, ohunogbingbingbinatieranosinsinsin

  4. ISE AGBE ODE - ONI • Awonagbe ode- oniniawonti o n lo awoneroigbalodelatisiseagbe • ORISIIRISII AGBE ODE – ONI. • Agbealaroje –won daokoohunjijelatipese fun ebi won. • Agbeolokonla –awonwonyii n daokolatifisise se. • Agbeolohunosin – awonti o n sin erankobiiMaluu. AdiyeatiElede.

  5. OHUN ELO ISE AGBE • OHUN ELO ISE AGBE AYE ATIJO Oko, Ada , Akoro, Aake, atiObe . • OHUN ELO ISE AGBE ODE-ONI • OogunajileEroigbalode – Katakata,eroiroleatiikobe. • Irugbintikiipe so. • Oogunajile.

  6. ORISIIRISII OKO • OKO EGAN – Ile aginjuti a seseda. Ile oloraa o dara fun gbingbinIgiowobiikokoorogbo, obi, robaatiope. • OKO ODAN – Ile pupa, o dara fun gbingbinohunjebiiagbado, ege, isu, eree, okaa-baba,owu, anamo. Egunsi, ata, ilaatiewebe. • OKO ODO/AKURO – Ile olomi. Okoebaodoni, o dara fun gbingbinagbado, ogede, ata,ilaatiewebebiiefoatiewedu.

  7. ITOJU IRE OKO • Ni aye atijoinuabatabi aka ni won maa n toju ire okosi. • NI aye ode-onioogunni won maa n fisi ire okoki o ma baa nikokoro. • PATAKI ISE AGBE • Ipeseohunjije fun awujo. • Ipeseise fun awoneniyan. • Ipeseohunelo fun awonile-isegbogbo. • Ipawowolesiapoijoba, paapaaloriawonohunti a bafisowosiokeokun.

  8. ILU LILU • Iran Ayanatiomoti won torolowoAyangalu lo n lulu. • Oruko to awononilumaa n je niAyanbunmi, Ayanleke, Ayandele, Alayanande, Ayangbemi , abblo. • Iseamuluudunniiseilulilu. DIE NINU ORISIIRISII ILU TI O WA NILE YORUBA. • Dundun, Gangan, Adamo, Ibembe, Igbin, Agere, IpeseOsugbo, Agogo, Apepe, Sanba, Sakara, Agidigbo, Aran atiKiriboto.

  9. OHUN ELO ILU • Igi, awo, atiosan • PATAKI ILU LILU • Fun ayeye – b.aisomoloruko, isinkuagba, igbeyawo, isile. Atiiwuye • Fun ijosin – b.abata fun sango. • Fun ipolowooja. • Fun kikioba. • Fun ogun - imoriyaatiitani-lolobo. • Fun ikede.

  10. ISE SISE • 1.Dahun ibeereti o wanioju ewe 105 (pg 105) iwe Simplified Yoruba L1 For J.S 1. latiowoAdewoyin S.Y. • 2. Yaorisiiilumarun-un ti o bawu o.

More Related