171 likes | 5.48k Views
ISE ISENBAYE. ISE AGBE ATI ISE ILU LILU. ORIKI ISE ISENBAYE. Ise isenbaye naa ni a mo si ISE ABINIBI. O je ise ti a jogun lati owo awon baba nla wa. APEERE ISE ISENBAYE Owo sise Ona sise Ope kiko Ise ila kiko Ise agbe , Ise ode, Ise ilu lilu , Ise agbede ,
E N D
ISE ISENBAYE ISE AGBE ATI ISE ILU LILU
ORIKI ISE ISENBAYE • Iseisenbayenaani a mo si ISE ABINIBI. • O je iseti a jogunlatiowoawonbabanlawa • APEERE ISE ISENBAYE • OwosiseOnasiseOpekikoIseilakiko • Iseagbe , Ise ode, Iseilulilu, Iseagbede, • Isearodida, Iseirundidi
. • AGBE AYE ATIJO • ORISIIRISII AGBE AYE ATIJO • AGBE ALAROJE– o n daokokekere fun ohunjejije. • Apeere ere oko re : ogede, agbado, isu. ege, eree, ataatiewebe. • AGBE OLOKO NLA- o n daokonlalatigbinohunjijeatiigiowobiikoko, ope, kofi, obi, orogbo, atiigiroba. • Won maa n lo eruatiiwofafun iseloko. • Awoniyawo, omoatiebinaamaa n ran won lowo. ISE AGBE • Iseagbe je iseokoriro, ohunogbingbingbinatieranosinsinsin
ISE AGBE ODE - ONI • Awonagbe ode- oniniawonti o n lo awoneroigbalodelatisiseagbe • ORISIIRISII AGBE ODE – ONI. • Agbealaroje –won daokoohunjijelatipese fun ebi won. • Agbeolokonla –awonwonyii n daokolatifisise se. • Agbeolohunosin – awonti o n sin erankobiiMaluu. AdiyeatiElede.
OHUN ELO ISE AGBE • OHUN ELO ISE AGBE AYE ATIJO Oko, Ada , Akoro, Aake, atiObe . • OHUN ELO ISE AGBE ODE-ONI • OogunajileEroigbalode – Katakata,eroiroleatiikobe. • Irugbintikiipe so. • Oogunajile.
ORISIIRISII OKO • OKO EGAN – Ile aginjuti a seseda. Ile oloraa o dara fun gbingbinIgiowobiikokoorogbo, obi, robaatiope. • OKO ODAN – Ile pupa, o dara fun gbingbinohunjebiiagbado, ege, isu, eree, okaa-baba,owu, anamo. Egunsi, ata, ilaatiewebe. • OKO ODO/AKURO – Ile olomi. Okoebaodoni, o dara fun gbingbinagbado, ogede, ata,ilaatiewebebiiefoatiewedu.
ITOJU IRE OKO • Ni aye atijoinuabatabi aka ni won maa n toju ire okosi. • NI aye ode-onioogunni won maa n fisi ire okoki o ma baa nikokoro. • PATAKI ISE AGBE • Ipeseohunjije fun awujo. • Ipeseise fun awoneniyan. • Ipeseohunelo fun awonile-isegbogbo. • Ipawowolesiapoijoba, paapaaloriawonohunti a bafisowosiokeokun.
ILU LILU • Iran Ayanatiomoti won torolowoAyangalu lo n lulu. • Oruko to awononilumaa n je niAyanbunmi, Ayanleke, Ayandele, Alayanande, Ayangbemi , abblo. • Iseamuluudunniiseilulilu. DIE NINU ORISIIRISII ILU TI O WA NILE YORUBA. • Dundun, Gangan, Adamo, Ibembe, Igbin, Agere, IpeseOsugbo, Agogo, Apepe, Sanba, Sakara, Agidigbo, Aran atiKiriboto.
OHUN ELO ILU • Igi, awo, atiosan • PATAKI ILU LILU • Fun ayeye – b.aisomoloruko, isinkuagba, igbeyawo, isile. Atiiwuye • Fun ijosin – b.abata fun sango. • Fun ipolowooja. • Fun kikioba. • Fun ogun - imoriyaatiitani-lolobo. • Fun ikede.
ISE SISE • 1.Dahun ibeereti o wanioju ewe 105 (pg 105) iwe Simplified Yoruba L1 For J.S 1. latiowoAdewoyin S.Y. • 2. Yaorisiiilumarun-un ti o bawu o.